IROYIN ATEJADE
*AISAN AJAKALE COVID-19 : AMORAN Pase iteti si ilana ti ijoba ipinle Ogun fi le le*
Lati dekun itankale ajakale arun agbaye ti gbogbo eniyan mo si COVID-19 iyen Coronavirus, Ijoba Ipinle Ogun labe Omooba Dapo Abiodun ti kede awon ona isora miran lati doju ija ko arun asekupani naa.
Awon ona isora yii ni fifi ofin de awon olokoda lati ma se gbe ju ero kan lo.
Ni ibamu pelu eyi, egbe Articulate Motorcycle Owners and Riders Association of Nigeria iyen (AMORAN) tii o faramo ipinu ijoba ipinle Ogun lati tun ojo ola wa se lapapo, ti palase fun gbogbo omo egba wa to n wa Okada fi sise aje lati maa gbe ju ero kan lo kii won si maa ko eti ikun si gbogbo ilana ti ijoba fi lele.
Ni afikun, a n ro gbogbo olokada ki won maa wo ibowo(gloves) ati ibomu (nose mask) bii won tii n gbe ero won kiri, lati ibikan si ibomiran.
Gbogbo ilana yii ni a gbodo maa tele, tori igboran san ju ebo riru lo. Olokada tii won ba mu a jebi, toripe ota ilu ni.
Gege bii apapo egbe AMORAN ti mo wipe ilera loro, bee ni a n ro gbogbo wa wipe igbogun tii ajakale arun coronavirus ni lati je ajose gbogbo wa.
Signed :
Otunba Taofeek Sokoya
Akowe Alukoro, AMORAN, Ogun State.
No comments:
Post a Comment